2 Àwọn Ọba 4:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Èlíṣà wá béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Kí ni kí n ṣe fún ọ? Sọ fún mi, kí lo ní sílé?” Ó fèsì pé: “Ìránṣẹ́ rẹ ò ní nǹkan kan nílé àfi ìṣà* òróró kan.”+
2 Èlíṣà wá béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Kí ni kí n ṣe fún ọ? Sọ fún mi, kí lo ní sílé?” Ó fèsì pé: “Ìránṣẹ́ rẹ ò ní nǹkan kan nílé àfi ìṣà* òróró kan.”+