-
Mátíù 10:41, 42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 Ẹnikẹ́ni tó bá gba wòlíì torí pé ó jẹ́ wòlíì máa gba èrè wòlíì,+ ẹnikẹ́ni tó bá sì gba olódodo torí pé ó jẹ́ olódodo máa gba èrè olódodo. 42 Ẹnikẹ́ni tó bá fún ọ̀kan nínú àwọn ẹni kékeré yìí ní ife omi tútù lásán pé kó mu ún, torí pé ó jẹ́ ọmọ ẹ̀yìn, lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, ó dájú pé kò ní pàdánù èrè rẹ̀.”+
-