Sáàmù 99:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mósè àti Áárónì wà lára àwọn àlùfáà rẹ̀,+Sámúẹ́lì sì wà lára àwọn tó ń ké pe orúkọ rẹ̀.+ Wọ́n ń pe Jèhófà,Ó sì ń dá wọn lóhùn.+
6 Mósè àti Áárónì wà lára àwọn àlùfáà rẹ̀,+Sámúẹ́lì sì wà lára àwọn tó ń ké pe orúkọ rẹ̀.+ Wọ́n ń pe Jèhófà,Ó sì ń dá wọn lóhùn.+