Jòhánù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹni yìí wá sọ́dọ̀ rẹ̀ ní òru,+ ó sì sọ fún un pé: “Rábì,+ a mọ̀ pé olùkọ́ tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni ọ́, torí kò sẹ́ni tó lè ṣe àwọn iṣẹ́ àmì+ tí ò ń ṣe yìí, àfi tí Ọlọ́run bá wà pẹ̀lú rẹ̀.”+
2 Ẹni yìí wá sọ́dọ̀ rẹ̀ ní òru,+ ó sì sọ fún un pé: “Rábì,+ a mọ̀ pé olùkọ́ tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni ọ́, torí kò sẹ́ni tó lè ṣe àwọn iṣẹ́ àmì+ tí ò ń ṣe yìí, àfi tí Ọlọ́run bá wà pẹ̀lú rẹ̀.”+