-
1 Àwọn Ọba 17:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Jèhófà bá a sọ̀rọ̀, ó ní: 3 “Kúrò ní ibí yìí, kí o forí lé ìlà oòrùn, kí o sì fara pa mọ́ sí Àfonífojì Kérítì, tó wà ní ìlà oòrùn Jọ́dánì.
-