-
Jóṣúà 19:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Alamélékì, Ámádì àti Míṣálì. Ó dé apá ìwọ̀ oòrùn lọ sí Kámẹ́lì,+ ó tún dé Ṣihori-líbínátì,
-
-
Jóṣúà 19:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Èyí ni ogún ẹ̀yà Áṣérì ní ìdílé-ìdílé.+ Èyí sì ni àwọn ìlú náà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-