Àwọn Onídàájọ́ 6:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Jóáṣì+ wá sọ fún gbogbo àwọn tó wá bá a pé: “Ṣé ẹ̀yin lẹ máa gbèjà Báálì ni? Àbí ẹ̀yin lẹ máa gbà á là? Ṣe la máa pa ẹnikẹ́ni tó bá gbèjà rẹ̀ láàárọ̀ yìí.+ Tó bá jẹ́ ọlọ́run ni, ẹ jẹ́ kó gbèjà ara rẹ̀,+ torí ẹnì kan ti wó pẹpẹ rẹ̀.”
31 Jóáṣì+ wá sọ fún gbogbo àwọn tó wá bá a pé: “Ṣé ẹ̀yin lẹ máa gbèjà Báálì ni? Àbí ẹ̀yin lẹ máa gbà á là? Ṣe la máa pa ẹnikẹ́ni tó bá gbèjà rẹ̀ láàárọ̀ yìí.+ Tó bá jẹ́ ọlọ́run ni, ẹ jẹ́ kó gbèjà ara rẹ̀,+ torí ẹnì kan ti wó pẹpẹ rẹ̀.”