ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 22:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Níkẹyìn, wọ́n dé ibi tí Ọlọ́run tòótọ́ sọ fún un, Ábúráhámù wá mọ pẹpẹ kan síbẹ̀, ó sì to igi sórí rẹ̀. Ó de Ísákì ọmọ rẹ̀ tọwọ́ tẹsẹ̀, ó sì gbé e sórí igi tó wà lórí pẹpẹ náà.+

  • Léfítíkù 1:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Kí àwọn ọmọ Áárónì, tí wọ́n jẹ́ àlùfáà, dá iná sórí pẹpẹ,+ kí wọ́n sì to igi sí iná náà. 8 Kí àwọn ọmọ Áárónì, tí wọ́n jẹ́ àlùfáà, to àwọn ègé ẹran náà+ sórí igi tó wà lórí iná lórí pẹpẹ, pẹ̀lú orí rẹ̀ àti ọ̀rá rẹ̀ líle.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́