-
1 Sámúẹ́lì 12:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Ni Sámúẹ́lì bá ké pe Jèhófà, Jèhófà wá sán ààrá, ó sì rọ òjò ní ọjọ́ yẹn, tí gbogbo àwọn èèyàn náà fi bẹ̀rù Jèhófà àti Sámúẹ́lì gidigidi.
-