1 Àwọn Ọba 18:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Ni Èlíjà bá sọ fún wọn pé: “Ẹ gbá àwọn wòlíì Báálì mú! Ẹ má ṣe jẹ́ kí ìkankan lára wọn sá lọ!” Ní kíá, wọ́n gbá wọn mú, Èlíjà wá mú wọn lọ sí odò* Kíṣónì,+ ó sì pa wọ́n níbẹ̀.+
40 Ni Èlíjà bá sọ fún wọn pé: “Ẹ gbá àwọn wòlíì Báálì mú! Ẹ má ṣe jẹ́ kí ìkankan lára wọn sá lọ!” Ní kíá, wọ́n gbá wọn mú, Èlíjà wá mú wọn lọ sí odò* Kíṣónì,+ ó sì pa wọ́n níbẹ̀.+