Hébérù 11:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Kí ni kí n tún sọ? Torí àkókò ò ní tó tí n bá ní kí n máa sọ̀rọ̀ nípa Gídíónì,+ Bárákì,+ Sámúsìn,+ Jẹ́fútà,+ Dáfídì,+ títí kan Sámúẹ́lì+ àti àwọn wòlíì yòókù. Hébérù 11:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 ayé ò sì yẹ wọ́n. Wọ́n rìn káàkiri nínú àwọn aṣálẹ̀, lórí àwọn òkè, nínú àwọn ihò àpáta àti àwọn ihò inú ilẹ̀.+
32 Kí ni kí n tún sọ? Torí àkókò ò ní tó tí n bá ní kí n máa sọ̀rọ̀ nípa Gídíónì,+ Bárákì,+ Sámúsìn,+ Jẹ́fútà,+ Dáfídì,+ títí kan Sámúẹ́lì+ àti àwọn wòlíì yòókù.
38 ayé ò sì yẹ wọ́n. Wọ́n rìn káàkiri nínú àwọn aṣálẹ̀, lórí àwọn òkè, nínú àwọn ihò àpáta àti àwọn ihò inú ilẹ̀.+