5 Jèhófà sọ̀ kalẹ̀+ nínú ìkùukùu, ó dúró sọ́dọ̀ rẹ̀ níbẹ̀, ó sì kéde orúkọ Jèhófà.+ 6 Jèhófà ń kọjá níwájú rẹ̀, ó sì ń kéde pé: “Jèhófà, Jèhófà, Ọlọ́run aláàánú,+ tó ń gba tẹni rò,+ tí kì í tètè bínú,+ tí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀+ àti òtítọ́+ rẹ̀ sì pọ̀ gidigidi,