Hósíà 13:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní báyìí, wọ́n dá ẹ̀ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀ Wọ́n sì fi fàdákà+ wọn ṣe ère onírin;*Wọ́n ṣe àwọn òrìṣà lọ́nà tó já fáfá, gbogbo rẹ̀ sì jẹ́ ohun tí oníṣẹ́ ọnà ṣe. Wọ́n sọ nípa wọn pé, ‘Kí àwọn tó wá rúbọ fi ẹnu ko àwọn ọmọ màlúù lẹ́nu.’+
2 Ní báyìí, wọ́n dá ẹ̀ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀ Wọ́n sì fi fàdákà+ wọn ṣe ère onírin;*Wọ́n ṣe àwọn òrìṣà lọ́nà tó já fáfá, gbogbo rẹ̀ sì jẹ́ ohun tí oníṣẹ́ ọnà ṣe. Wọ́n sọ nípa wọn pé, ‘Kí àwọn tó wá rúbọ fi ẹnu ko àwọn ọmọ màlúù lẹ́nu.’+