ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 8:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Lẹ́yìn náà, Dáfídì fi àwọn àwùjọ ọmọ ogun àdádó sí Damásíkù ní Síríà, àwọn ará Síríà wá di ìránṣẹ́ Dáfídì, wọ́n sì ń mú ìṣákọ́lẹ̀* wá. Jèhófà sì ń jẹ́ kí Dáfídì ṣẹ́gun* ní ibikíbi tó bá lọ.+

  • 2 Àwọn Ọba 5:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ìgbà kan wà tí àwọn ará Síríà lọ kó ohun ìní àwọn èèyàn, wọ́n mú ọmọbìnrin kékeré kan lẹ́rú láti ilẹ̀ Ísírẹ́lì, ó sì di ìránṣẹ́ ìyàwó Náámánì.

  • Àìsáyà 9:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Síríà láti ìlà oòrùn àti àwọn Filísínì láti ìwọ̀ oòrùn,*+

      Wọ́n máa la ẹnu wọn, wọ́n á sì jẹ Ísírẹ́lì run.+

      Pẹ̀lú gbogbo èyí, ìbínú rẹ̀ kò tíì yí pa dà,

      Àmọ́ ó ṣì na ọwọ́ rẹ̀ jáde láti lù wọ́n.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́