2 Àwọn Ọba 13:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó wá sọ pé: “Ṣí fèrèsé* tó dojú kọ ìlà oòrùn.” Torí náà, ó ṣí i. Èlíṣà sọ pé: “Ta á!” Nítorí náà, ó ta á. Ló bá sọ pé: “Ọfà ìṣẹ́gun* Jèhófà, ọfà ìṣẹ́gun* lórí Síríà! Wàá ṣá Síríà balẹ̀* ní Áfékì+ títí wàá fi pa á run.”
17 Ó wá sọ pé: “Ṣí fèrèsé* tó dojú kọ ìlà oòrùn.” Torí náà, ó ṣí i. Èlíṣà sọ pé: “Ta á!” Nítorí náà, ó ta á. Ló bá sọ pé: “Ọfà ìṣẹ́gun* Jèhófà, ọfà ìṣẹ́gun* lórí Síríà! Wàá ṣá Síríà balẹ̀* ní Áfékì+ títí wàá fi pa á run.”