Míkà 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Àwọn tó ń gbìmọ̀ ìkà gbé,Tí wọ́n ń gbèrò ibi lórí ibùsùn wọn! Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, wọ́n ṣe ohun tí wọ́n gbèrò,Torí pé agbára wọn ká a.+ Míkà 7:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n mọ iṣẹ́ ibi ṣe dáadáa;+Olórí ń béèrè nǹkan lọ́wọ́ àwọn èèyàn,Adájọ́ ń béèrè àbẹ̀tẹ́lẹ̀,+Gbajúmọ̀ ń sọ ohun tó fẹ́,*+Wọ́n sì jọ gbìmọ̀ pọ̀.*
2 “Àwọn tó ń gbìmọ̀ ìkà gbé,Tí wọ́n ń gbèrò ibi lórí ibùsùn wọn! Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, wọ́n ṣe ohun tí wọ́n gbèrò,Torí pé agbára wọn ká a.+
3 Wọ́n mọ iṣẹ́ ibi ṣe dáadáa;+Olórí ń béèrè nǹkan lọ́wọ́ àwọn èèyàn,Adájọ́ ń béèrè àbẹ̀tẹ́lẹ̀,+Gbajúmọ̀ ń sọ ohun tó fẹ́,*+Wọ́n sì jọ gbìmọ̀ pọ̀.*