-
1 Àwọn Ọba 14:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Èèyàn Jèróbóámù èyíkéyìí tí ó bá kú sí ìlú ni ajá yóò jẹ; èyí tí ó bá sì kú sí pápá ni àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run yóò jẹ, nítorí Jèhófà ti sọ ọ́.”’
-
-
1 Àwọn Ọba 16:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ajá ni yóò jẹ ará ilé Bááṣà èyíkéyìí tí ó bá kú sínú ìlú; àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run ni yóò sì jẹ ará ilé rẹ̀ èyíkéyìí tí ó bá kú sí pápá.”
-