-
2 Kíróníkà 18:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Àmọ́, Jèhóṣáfátì sọ fún ọba Ísírẹ́lì pé: “Jọ̀wọ́, kọ́kọ́ wádìí ọ̀rọ̀ lọ́dọ̀ Jèhófà.”+ 5 Torí náà, ọba Ísírẹ́lì kó àwọn wòlíì jọ, ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ọkùnrin, ó sì bi wọ́n pé: “Ṣé ká lọ bá Ramoti-gílíádì jà tàbí ká má lọ?” Wọ́n dá a lóhùn pé: “Lọ, Ọlọ́run tòótọ́ yóò sì fi í lé ọba lọ́wọ́.”
-