Ìsíkíẹ́lì 13:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ọmọ èèyàn, sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí àwọn wòlíì Ísírẹ́lì,+ kí o sì sọ fún àwọn tó ń hùmọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ tiwọn* pé,+ ‘Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà. 3 Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Ẹ gbé, ẹ̀yin òmùgọ̀ wòlíì, tí ẹ̀ ń sọ èrò ọkàn yín, láìrí nǹkan kan!+
2 “Ọmọ èèyàn, sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí àwọn wòlíì Ísírẹ́lì,+ kí o sì sọ fún àwọn tó ń hùmọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ tiwọn* pé,+ ‘Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà. 3 Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Ẹ gbé, ẹ̀yin òmùgọ̀ wòlíì, tí ẹ̀ ń sọ èrò ọkàn yín, láìrí nǹkan kan!+