-
Ìsíkíẹ́lì 14:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 “‘Àmọ́ tí a bá tan wòlíì náà, tó sì fún un lésì, èmi Jèhófà ló tàn án.+ Màá wá na ọwọ́ mi kí n lè fìyà jẹ ẹ́, màá sì pa á run kúrò láàárín àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.
-