-
2 Kíróníkà 17:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Jèhófà wà pẹ̀lú Jèhóṣáfátì nítorí pé ó rìn ní àwọn ọ̀nà tí Dáfídì+ baba ńlá rẹ̀ rìn nígbà àtijọ́, kò sì wá àwọn Báálì.