1 Àwọn Ọba 15:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ásà ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Jèhófà,+ bíi Dáfídì baba ńlá rẹ̀. 12 Ó lé àwọn aṣẹ́wó ọkùnrin tó wà ní tẹ́ńpìlì kúrò ní ilẹ̀ náà,+ ó sì mú gbogbo òrìṣà ẹ̀gbin* tí àwọn baba ńlá rẹ̀ ṣe kúrò.+
11 Ásà ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Jèhófà,+ bíi Dáfídì baba ńlá rẹ̀. 12 Ó lé àwọn aṣẹ́wó ọkùnrin tó wà ní tẹ́ńpìlì kúrò ní ilẹ̀ náà,+ ó sì mú gbogbo òrìṣà ẹ̀gbin* tí àwọn baba ńlá rẹ̀ ṣe kúrò.+