-
2 Kíróníkà 21:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Níkẹyìn, Jèhóṣáfátì sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀, wọ́n sì sin ín pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀ sí Ìlú Dáfídì; Jèhórámù ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.+
-
-
2 Kíróníkà 21:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ẹni ọdún méjìlélọ́gbọ̀n (32) ni Jèhórámù nígbà tó jọba, ọdún mẹ́jọ ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+
-