2 Sámúẹ́lì 3:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Kí ó yí dà sórí Jóábù+ àti gbogbo ilé bàbá rẹ̀. Kí ọkùnrin tí nǹkan ń dà lára rẹ̀+ tàbí tí ó jẹ́ adẹ́tẹ̀ + tàbí tí ó yarọ* tàbí ẹni tí idà pa tàbí ẹni tí kò ní oúnjẹ+ má sì tán nílé Jóábù!”
29 Kí ó yí dà sórí Jóábù+ àti gbogbo ilé bàbá rẹ̀. Kí ọkùnrin tí nǹkan ń dà lára rẹ̀+ tàbí tí ó jẹ́ adẹ́tẹ̀ + tàbí tí ó yarọ* tàbí ẹni tí idà pa tàbí ẹni tí kò ní oúnjẹ+ má sì tán nílé Jóábù!”