Jẹ́nẹ́sísì 19:36, 37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Àwọn ọmọbìnrin Lọ́ọ̀tì méjèèjì lóyún nípasẹ̀ bàbá wọn. 37 Èyí àkọ́bí bí ọmọkùnrin kan, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Móábù.+ Òun ló wá di bàbá àwọn ọmọ Móábù.+ 2 Sámúẹ́lì 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó ṣẹ́gun àwọn ọmọ Móábù,+ ó dá wọn dùbúlẹ̀, ó sì fi okùn wọ̀n wọ́n. Ó ní kí wọ́n pa àwọn tó wà níbi tí okùn ìwọ̀n méjì gùn dé, àmọ́ kí wọ́n dá àwọn tó wà níbi okùn ìwọ̀n kan sí.+ Àwọn ọmọ Móábù di ìránṣẹ́ Dáfídì, wọ́n sì ń mú ìṣákọ́lẹ̀*+ wá. Sáàmù 60:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Móábù ni bàsíà tí mo fi ń wẹ ẹsẹ̀.+ Orí Édómù ni màá ju bàtà mi sí.+ Màá kígbe ìṣẹ́gun lórí Filísíà.”+
36 Àwọn ọmọbìnrin Lọ́ọ̀tì méjèèjì lóyún nípasẹ̀ bàbá wọn. 37 Èyí àkọ́bí bí ọmọkùnrin kan, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Móábù.+ Òun ló wá di bàbá àwọn ọmọ Móábù.+
2 Ó ṣẹ́gun àwọn ọmọ Móábù,+ ó dá wọn dùbúlẹ̀, ó sì fi okùn wọ̀n wọ́n. Ó ní kí wọ́n pa àwọn tó wà níbi tí okùn ìwọ̀n méjì gùn dé, àmọ́ kí wọ́n dá àwọn tó wà níbi okùn ìwọ̀n kan sí.+ Àwọn ọmọ Móábù di ìránṣẹ́ Dáfídì, wọ́n sì ń mú ìṣákọ́lẹ̀*+ wá.
8 Móábù ni bàsíà tí mo fi ń wẹ ẹsẹ̀.+ Orí Édómù ni màá ju bàtà mi sí.+ Màá kígbe ìṣẹ́gun lórí Filísíà.”+