-
Lúùkù 9:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Torí náà, gbogbo wọn jẹ, wọ́n yó, wọ́n sì kó èyí tó ṣẹ́ kù jọ, ó kún apẹ̀rẹ̀ méjìlá (12).+
-
-
Jòhánù 6:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Torí náà, lẹ́yìn tí àwọn tó jẹ látinú búrẹ́dì ọkà báálì márùn-ún náà jẹun tán, wọ́n kó ohun tó ṣẹ́ kù jọ, ó sì kún apẹ̀rẹ̀ méjìlá (12).
-