-
Ìṣe 5:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Pétérù sọ fún un pé: “Sọ fún mi, ṣé iye tí ẹ̀yin méjèèjì ta ilẹ̀ náà nìyí?” Ó sọ pé: “Bẹ́ẹ̀ ni, iye rẹ̀ nìyẹn.” 9 Ni Pétérù bá sọ fún un pé: “Kí ló dé tí ẹ̀yin méjèèjì fi fohùn ṣọ̀kan láti dán ẹ̀mí Jèhófà* wò? Wò ó! Àwọn tó lọ sin ọkọ rẹ ti wà lẹ́nu ọ̀nà, wọ́n á gbé ìwọ náà jáde.”
-