2 Àwọn Ọba 8:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ní ọdún karùn-ún Jèhórámù+ ọmọ Áhábù ọba Ísírẹ́lì, nígbà tí Jèhóṣáfátì ṣì jẹ́ ọba Júdà, Jèhórámù+ ọmọ Jèhóṣáfátì ọba Júdà, di ọba.
16 Ní ọdún karùn-ún Jèhórámù+ ọmọ Áhábù ọba Ísírẹ́lì, nígbà tí Jèhóṣáfátì ṣì jẹ́ ọba Júdà, Jèhórámù+ ọmọ Jèhóṣáfátì ọba Júdà, di ọba.