-
2 Sámúẹ́lì 5:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Tí o bá ti gbọ́ ìró tó ń dún bí ìró ẹsẹ̀ lórí àwọn igi bákà, kí o gbé ìgbésẹ̀ ní kíá, nítorí Jèhófà yóò ti lọ ṣáájú rẹ láti ṣá àwọn ọmọ ogun Filísínì balẹ̀.”
-