ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 10:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Lákòókò yẹn, Jèhófà bẹ̀rẹ̀ sí í gé* ìpínlẹ̀ Ísírẹ́lì kù. Hásáẹ́lì ń kọ lù wọ́n léraléra káàkiri ìpínlẹ̀ Ísírẹ́lì,+

  • 2 Àwọn Ọba 12:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ìgbà náà ni Hásáẹ́lì+ ọba Síríà lọ bá Gátì+ jà, ó sì gbà á, lẹ́yìn náà ó pinnu láti gbéjà ko Jerúsálẹ́mù.*+

  • 2 Àwọn Ọba 13:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Torí náà, ìbínú Jèhófà+ ru sí Ísírẹ́lì,+ ó sì fi wọ́n lé ọwọ́ Hásáẹ́lì+ ọba Síríà àti Bẹni-hádádì+ ọmọ Hásáẹ́lì ní gbogbo ìgbà náà.

  • Émọ́sì 1:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,

      ‘“Nítorí ìdìtẹ̀* mẹ́ta Damásíkù àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,

      Nítorí wọ́n fi ohun èlò ìpakà onírin pa Gílíádì bí ọkà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́