2 Àwọn Ọba 4:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Nígbà tí Èlíṣà pa dà sí Gílígálì, ìyàn mú ní ilẹ̀ náà.+ Àwọn ọmọ wòlíì+ jókòó níwájú rẹ̀, ó sì sọ fún ìránṣẹ́ rẹ̀ pé:+ “Gbé ìkòkò ńlá kaná, kí o sì se ọbẹ̀ fún àwọn ọmọ wòlíì.”
38 Nígbà tí Èlíṣà pa dà sí Gílígálì, ìyàn mú ní ilẹ̀ náà.+ Àwọn ọmọ wòlíì+ jókòó níwájú rẹ̀, ó sì sọ fún ìránṣẹ́ rẹ̀ pé:+ “Gbé ìkòkò ńlá kaná, kí o sì se ọbẹ̀ fún àwọn ọmọ wòlíì.”