ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 6:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Ìgbà yẹn ni Jóṣúà búra* pé: “Níwájú Jèhófà, ègún ni fún ẹni tó bá gbìyànjú láti tún ìlú Jẹ́ríkò yìí kọ́. Tó bá fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ lélẹ̀, ẹ̀mí àkọ́bí rẹ̀ ló máa fi dí i, tó bá sì gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ nàró, ẹ̀mí àbíkẹ́yìn rẹ̀ ló máa fi dí i.”+

  • 1 Àwọn Ọba 16:34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Nígbà tí Áhábù ń jọba, Híélì ará Bẹ́tẹ́lì tún Jẹ́ríkò kọ́. Ẹ̀mí Ábírámù àkọ́bí rẹ̀ ló fi dí i nígbà tó fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ lélẹ̀, ẹ̀mí Ségúbù àbíkẹ́yìn rẹ̀ ló sì fi dí i nígbà tó gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ nàró, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà gbẹnu Jóṣúà ọmọ Núnì sọ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́