1 Àwọn Ọba 21:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kí o sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “O ti pa ọkùnrin yìí+ o sì ti sọ nǹkan ìní rẹ̀ di tìrẹ,* àbí?”’+ Kí o wá sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ibi tí àwọn ajá ti lá ẹ̀jẹ̀ Nábótì, ni àwọn ajá ti máa lá ẹ̀jẹ̀ rẹ.”’”+
19 Kí o sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “O ti pa ọkùnrin yìí+ o sì ti sọ nǹkan ìní rẹ̀ di tìrẹ,* àbí?”’+ Kí o wá sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ibi tí àwọn ajá ti lá ẹ̀jẹ̀ Nábótì, ni àwọn ajá ti máa lá ẹ̀jẹ̀ rẹ.”’”+