ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 1:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ni Dáfídì bá di ẹ̀wù ara rẹ̀ mú, ó sì fà á ya, gbogbo àwọn ọkùnrin tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ náà sì ṣe bẹ́ẹ̀. 12 Wọ́n pohùn réré ẹkún, wọ́n sunkún, wọ́n sì gbààwẹ̀+ títí di ìrọ̀lẹ́ nítorí Sọ́ọ̀lù àti Jónátánì ọmọ rẹ̀ àti nítorí àwọn èèyàn Jèhófà àti ilé Ísírẹ́lì+ torí pé wọ́n ti fi idà pa wọ́n.

  • Jóòbù 1:19, 20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Ni ìjì tó lágbára bá fẹ́ wá lójijì láti aginjù, ó fẹ́ lu igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ilé náà, ilé náà sì wó lu àwọn ọmọ náà, wọ́n sì kú. Èmi nìkan ló yè bọ́, tí mo sì wá sọ fún ọ.”

      20 Ni Jóòbù bá dìde, ó fa aṣọ rẹ̀ ya, ó gé irun orí rẹ̀; ó wólẹ̀, ó sì forí balẹ̀,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́