-
1 Àwọn Ọba 8:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Sólómọ́nì wá dúró níwájú pẹpẹ Jèhófà ní iwájú gbogbo ìjọ Ísírẹ́lì, ó tẹ́ ọwọ́ rẹ̀ sí ọ̀run,+
-
-
2 Kíróníkà 4:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Lẹ́yìn náà, ó ṣe pẹpẹ bàbà,+ gígùn rẹ̀ jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá.
-