Jóṣúà 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 gbàrà tí àtẹ́lẹsẹ̀ àwọn àlùfáà tó gbé Àpótí Jèhófà, Olúwa gbogbo ayé bá kan* omi Jọ́dánì, omi Jọ́dánì tó ń ṣàn wá látòkè máa dáwọ́ dúró, ó sì máa dúró bí ìsédò.”*+ 2 Àwọn Ọba 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nígbà náà, Èlíjà mú ẹ̀wù oyè rẹ̀,+ ó ká a, ó sì lu omi náà, ó pín sápá ọ̀tún àti sápá òsì, tó fi jẹ́ pé àwọn méjèèjì gba orí ilẹ̀ gbígbẹ sọdá.+
13 gbàrà tí àtẹ́lẹsẹ̀ àwọn àlùfáà tó gbé Àpótí Jèhófà, Olúwa gbogbo ayé bá kan* omi Jọ́dánì, omi Jọ́dánì tó ń ṣàn wá látòkè máa dáwọ́ dúró, ó sì máa dúró bí ìsédò.”*+
8 Nígbà náà, Èlíjà mú ẹ̀wù oyè rẹ̀,+ ó ká a, ó sì lu omi náà, ó pín sápá ọ̀tún àti sápá òsì, tó fi jẹ́ pé àwọn méjèèjì gba orí ilẹ̀ gbígbẹ sọdá.+