5 Torí náà, ó kó àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì jọ, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ lọ sí àwọn ìlú Júdà kí ẹ sì gba owó lọ́wọ́ gbogbo Ísírẹ́lì láti máa fi tún ilé Ọlọ́run yín+ ṣe lọ́dọọdún; kí ẹ sì tètè gbé ìgbésẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ náà.” Àmọ́, àwọn ọmọ Léfì kò tètè gbé ìgbésẹ̀.+