2 Kíróníkà 24:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nítorí náà, ọba pe Jèhóádà olórí, ó sì sọ fún un pé:+ “Kí ló dé tí o kò tíì ní kí àwọn ọmọ Léfì mú owó orí mímọ́ tí Mósè+ ìránṣẹ́ Jèhófà pa láṣẹ wá láti Júdà àti Jerúsálẹ́mù, ìyẹn owó orí mímọ́ ti ìjọ Ísírẹ́lì, fún àgọ́ Ẹ̀rí?+
6 Nítorí náà, ọba pe Jèhóádà olórí, ó sì sọ fún un pé:+ “Kí ló dé tí o kò tíì ní kí àwọn ọmọ Léfì mú owó orí mímọ́ tí Mósè+ ìránṣẹ́ Jèhófà pa láṣẹ wá láti Júdà àti Jerúsálẹ́mù, ìyẹn owó orí mímọ́ ti ìjọ Ísírẹ́lì, fún àgọ́ Ẹ̀rí?+