Nọ́ńbà 13:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Torí náà, wọ́n gòkè lọ, wọ́n sì ṣe amí ilẹ̀ náà láti aginjù Síínì+ dé Réhóbù+ ní tòsí Lebo-hámátì.*+ Nọ́ńbà 34:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Fi ìtọ́ni yìí tó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé, ‘Tí ẹ bá wọ ilẹ̀ Kénáánì,+ ilẹ̀ tó máa di tiyín nìyí láwọn ibi tí ààlà+ rẹ̀ dé. Nọ́ńbà 34:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “‘Èyí ni yóò jẹ́ ààlà yín ní àríwá: Kí ẹ pààlà yín láti Òkun Ńlá dé Òkè Hóórì. 8 Kí ẹ pààlà yín láti Òkè Hóórì dé Lebo-hámátì,*+ kí ààlà náà sì parí sí Sédádì.+
21 Torí náà, wọ́n gòkè lọ, wọ́n sì ṣe amí ilẹ̀ náà láti aginjù Síínì+ dé Réhóbù+ ní tòsí Lebo-hámátì.*+
2 “Fi ìtọ́ni yìí tó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé, ‘Tí ẹ bá wọ ilẹ̀ Kénáánì,+ ilẹ̀ tó máa di tiyín nìyí láwọn ibi tí ààlà+ rẹ̀ dé.
7 “‘Èyí ni yóò jẹ́ ààlà yín ní àríwá: Kí ẹ pààlà yín láti Òkun Ńlá dé Òkè Hóórì. 8 Kí ẹ pààlà yín láti Òkè Hóórì dé Lebo-hámátì,*+ kí ààlà náà sì parí sí Sédádì.+