2 Àwọn Ọba 14:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Lẹ́yìn náà, gbogbo àwọn èèyàn Júdà mú Asaráyà*+ tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún (16),+ wọ́n sì fi í jọba ní ipò Amasááyà bàbá rẹ̀.+
21 Lẹ́yìn náà, gbogbo àwọn èèyàn Júdà mú Asaráyà*+ tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún (16),+ wọ́n sì fi í jọba ní ipò Amasááyà bàbá rẹ̀.+