2 Àwọn Ọba 15:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Lẹ́yìn náà, Hóṣéà+ ọmọ Élà dìtẹ̀ mọ́ Pékà ọmọ Remaláyà, ó ṣá a balẹ̀, ó sì pa á; ó jọba ní ipò rẹ̀ ní ogún ọdún Jótámù+ ọmọ Ùsáyà.
30 Lẹ́yìn náà, Hóṣéà+ ọmọ Élà dìtẹ̀ mọ́ Pékà ọmọ Remaláyà, ó ṣá a balẹ̀, ó sì pa á; ó jọba ní ipò rẹ̀ ní ogún ọdún Jótámù+ ọmọ Ùsáyà.