Hósíà 12:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ̀tàn*+ àti àìṣòótọ́ ti wà ní Gílíádì. Wọ́n ti fi àwọn akọ màlúù rúbọ ní Gílígálì,+Àwọn pẹpẹ wọn sì dà bí àwọn òkúta tí a tò jọ sí àárín àwọn ebè inú oko.+
11 Ẹ̀tàn*+ àti àìṣòótọ́ ti wà ní Gílíádì. Wọ́n ti fi àwọn akọ màlúù rúbọ ní Gílígálì,+Àwọn pẹpẹ wọn sì dà bí àwọn òkúta tí a tò jọ sí àárín àwọn ebè inú oko.+