1 Kíróníkà 10:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bí Sọ́ọ̀lù ṣe kú nìyẹn nítorí ìwà àìṣòótọ́ tó hù sí Jèhófà torí pé kò ṣe ohun tí Jèhófà+ sọ àti pé ó lọ wádìí lọ́dọ̀ abẹ́mìílò+ 14 dípò kó wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà. Torí náà, Ó pa á, ó sì gbé ìjọba náà fún Dáfídì ọmọ Jésè.+
13 Bí Sọ́ọ̀lù ṣe kú nìyẹn nítorí ìwà àìṣòótọ́ tó hù sí Jèhófà torí pé kò ṣe ohun tí Jèhófà+ sọ àti pé ó lọ wádìí lọ́dọ̀ abẹ́mìílò+ 14 dípò kó wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà. Torí náà, Ó pa á, ó sì gbé ìjọba náà fún Dáfídì ọmọ Jésè.+