34 Títí di òní yìí, ẹ̀sìn wọn àtẹ̀yìnwá ni wọ́n ń ṣe. Kò sí ìkankan lára wọn tó sin Jèhófà, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ìkankan lára wọn tó tẹ̀ lé ìlànà rẹ̀ àti ìdájọ́ rẹ̀, wọn ò sì pa Òfin àti àṣẹ tí Jèhófà fún àwọn ọmọ Jékọ́bù mọ́, ẹni tí Ó yí orúkọ rẹ̀ pa dà sí Ísírẹ́lì.+