-
2 Àwọn Ọba 20:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 “Mo bẹ̀ ọ́, Jèhófà, jọ̀ọ́ rántí bí mo ṣe fi òtítọ́ àti gbogbo ọkàn mi rìn níwájú rẹ, ohun tó dáa ní ojú rẹ sì ni mo ṣe.”+ Hẹsikáyà sì bẹ̀rẹ̀ sí í sunkún pẹ̀rẹ̀pẹ̀rẹ̀.
-
-
2 Kíróníkà 31:20, 21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Hẹsikáyà ṣe gbogbo nǹkan yìí káàkiri Júdà, ó ń ṣe ohun tó dáa, tí ó tọ́, tí ó sì jẹ́ òdodo níwájú Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀. 21 Nínú gbogbo iṣẹ́ tó ṣe láti wá Ọlọ́run rẹ̀, bóyá èyí tó jẹ mọ́ iṣẹ́ ìsìn ilé Ọlọ́run tòótọ́+ tàbí ti Òfin àti àṣẹ, gbogbo ọkàn rẹ̀ ló fi ṣe é, ó sì ṣàṣeyọrí.
-