1 Àwọn Ọba 18:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Àmọ́, Jèhófà fún Èlíjà lágbára, ó wé* aṣọ rẹ̀ mọ́ ìbàdí, ó sì ń sáré lọ níwájú Áhábù títí dé Jésírẹ́lì. Ìsíkíẹ́lì 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jèhófà bá Ìsíkíẹ́lì* ọmọ àlùfáà Búúsì sọ̀rọ̀ lẹ́bàá odò Kébárì ní ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà.+ Ọwọ́ Jèhófà sì wá sórí rẹ̀ níbẹ̀.+ Ìṣe 11:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Yàtọ̀ síyẹn, ọwọ́ Jèhófà* wà lára wọn, ọ̀pọ̀ èèyàn di onígbàgbọ́, wọ́n sì yíjú sí Olúwa.+
46 Àmọ́, Jèhófà fún Èlíjà lágbára, ó wé* aṣọ rẹ̀ mọ́ ìbàdí, ó sì ń sáré lọ níwájú Áhábù títí dé Jésírẹ́lì.
3 Jèhófà bá Ìsíkíẹ́lì* ọmọ àlùfáà Búúsì sọ̀rọ̀ lẹ́bàá odò Kébárì ní ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà.+ Ọwọ́ Jèhófà sì wá sórí rẹ̀ níbẹ̀.+