-
2 Àwọn Ọba 3:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Wọ́n wó ìlú náà palẹ̀, àwọn ọkùnrin náà lọ́kọ̀ọ̀kan sì ju òkúta sórí gbogbo ilẹ̀ tó dára, títí òkúta fi kún gbogbo ilẹ̀ náà; wọ́n dí gbogbo orísun omi pa,+ wọ́n sì gé gbogbo igi tó dára lulẹ̀.+ Níkẹyìn, àwọn ògiri olókùúta Kiri-hárésétì+ nìkan ló ṣẹ́ kù ní ìdúró, àwọn tó ń ta kànnàkànnà yí i ká, wọ́n sì wó o lulẹ̀.
-