Ẹ́sírà 4:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 ẹsẹ̀kẹsẹ̀ ni wọ́n lọ bá Serubábélì àti àwọn olórí agbo ilé, wọ́n sì sọ fún wọn pé: “Ẹ jẹ́ ká jọ kọ́ ilé yìí; nítorí Ọlọ́run yín làwa náà ń sìn,*+ òun la sì ń rúbọ sí láti ìgbà ayé Esari-hádónì+ ọba Ásíríà tó kó wa wá síbí.”+
2 ẹsẹ̀kẹsẹ̀ ni wọ́n lọ bá Serubábélì àti àwọn olórí agbo ilé, wọ́n sì sọ fún wọn pé: “Ẹ jẹ́ ká jọ kọ́ ilé yìí; nítorí Ọlọ́run yín làwa náà ń sìn,*+ òun la sì ń rúbọ sí láti ìgbà ayé Esari-hádónì+ ọba Ásíríà tó kó wa wá síbí.”+