2 Àwọn Ọba 19:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 “Màá gbèjà ìlú yìí,+ màá sì gbà á sílẹ̀ nítorí orúkọ mi+Àti nítorí Dáfídì ìránṣẹ́ mi.”’”+ Àìsáyà 37:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 ‘Màá gbèjà ìlú yìí,+ màá sì gbà á sílẹ̀ nítorí orúkọ mi+Àti nítorí Dáfídì ìránṣẹ́ mi.’”+