ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 12:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Wọn kì í sọ pé kí àwọn ọkùnrin náà ṣe ìṣirò owó tí wọ́n ní kí wọ́n fún àwọn òṣìṣẹ́, torí pé wọ́n ṣeé fọkàn tán.+

  • 2 Kíróníkà 34:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Àwọn ọkùnrin náà fi òótọ́ inú ṣe iṣẹ́ náà.+ Àwọn ọmọ Léfì tí wọ́n yàn láti jẹ́ alábòójútó wọn ni Jáhátì àti Ọbadáyà látinú àwọn ọmọ Mérárì+ àti Sekaráyà pẹ̀lú Méṣúlámù látinú àwọn ọmọ Kóhátì.+ Àwọn ọmọ Léfì, tí gbogbo wọn jẹ́ olórin tó mọṣẹ́ orin,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́